Sekaráyà 14:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ní ọjọ́ yẹn, omi ìyè+ yóò ṣàn jáde láti Jerúsálẹ́mù,+ ìdajì rẹ̀ sí ọ̀nà òkun ìlà oòrùn*+ àti ìdajì rẹ̀ sí ọ̀nà òkun ìwọ̀ oòrùn.*+ Yóò ṣẹlẹ̀ ní ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn àti ní ìgbà òtútù.
8 Ní ọjọ́ yẹn, omi ìyè+ yóò ṣàn jáde láti Jerúsálẹ́mù,+ ìdajì rẹ̀ sí ọ̀nà òkun ìlà oòrùn*+ àti ìdajì rẹ̀ sí ọ̀nà òkun ìwọ̀ oòrùn.*+ Yóò ṣẹlẹ̀ ní ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn àti ní ìgbà òtútù.