Diutarónómì 32:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Wọ́n fi àwọn ọlọ́run àjèjì+ mú un bínú;Wọ́n ń fi àwọn ohun ìríra+ múnú bí i.