Ìsíkíẹ́lì 16:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 O tún mú ohun ọ̀ṣọ́ wúrà àti fàdákà tí mo fún ọ, o fi ṣe àwọn ère ọkùnrin fún ara rẹ, o sì bá wọn ṣèṣekúṣe.+ 18 O fi aṣọ rẹ tí wọ́n kó iṣẹ́ sí bò wọ́n,* o sì fi òróró àti tùràrí mi rúbọ sí wọn.+
17 O tún mú ohun ọ̀ṣọ́ wúrà àti fàdákà tí mo fún ọ, o fi ṣe àwọn ère ọkùnrin fún ara rẹ, o sì bá wọn ṣèṣekúṣe.+ 18 O fi aṣọ rẹ tí wọ́n kó iṣẹ́ sí bò wọ́n,* o sì fi òróró àti tùràrí mi rúbọ sí wọn.+