-
Àìsáyà 57:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ẹ̀yìn ilẹ̀kùn àti férémù ilẹ̀kùn lo gbé ìrántí rẹ kalẹ̀ sí.
O fi mí sílẹ̀, o sì ṣí ara rẹ sílẹ̀;
O lọ, o sì mú kí ibùsùn rẹ fẹ̀ dáadáa.
O sì bá wọn dá májẹ̀mú.
-