25 Ibi tó gbàfiyèsí jù ní gbogbo ojú ọ̀nà lo kọ́ àwọn ibi gíga rẹ sí, o sì sọ ẹwà rẹ di ohun ìríra bí o ṣe ń bá gbogbo àwọn tó ń kọjá lọ ṣèṣekúṣe,*+ o sì wá jingíri sínú iṣẹ́ aṣẹ́wó.+
33 Àwọn èèyàn ló máa ń fún aṣẹ́wó lẹ́bùn+ àmọ́ ìwọ lò ń fún gbogbo àwọn tó ń bá ọ ṣèṣekúṣe lẹ́bùn,+ o tún fún wọn ní àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n lè wá bá ọ ṣèṣekúṣe láti ibi gbogbo.+
18 “Nígbà tí kò fi iṣẹ́ aṣẹ́wó rẹ̀ bò mọ́, tó sì ń tú ara rẹ̀ sí ìhòòhò,+ mo kórìíra rẹ̀, mo sì fi í sílẹ̀, bí mo ṣe kórìíra ẹ̀gbọ́n rẹ̀ tí mo* sì fi í sílẹ̀.+