-
Sáàmù 106:39, 40Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
39 Àwọn iṣẹ́ wọn sọ wọ́n di aláìmọ́,
Wọ́n sì ṣe àgbèrè ẹ̀sìn.+
40 Torí náà, ìbínú Jèhófà ru sí àwọn èèyàn rẹ̀,
Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í kórìíra ogún rẹ̀.
-
-
Jeremáyà 12:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ogún mi ti dà bíi kìnnìún inú igbó sí mi.
Ó ti bú mọ́ mi.
Ìdí nìyẹn tí mo fi kórìíra rẹ̀.
-