Léfítíkù 26:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 “‘Nígbà yẹn, ilẹ̀ náà yóò san àwọn sábáàtì rẹ̀ ní gbogbo ọjọ́ tó bá fi wà ní ahoro, nígbà tí ẹ bá wà ní ilẹ̀ àwọn ọ̀tá yín. Nígbà yẹn, ilẹ̀ náà máa sinmi,* torí ó gbọ́dọ̀ san àwọn sábáàtì rẹ̀ pa dà.+ Jeremáyà 9:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Màá sọ Jerúsálẹ́mù di òkìtì òkúta,+ ibùgbé àwọn ajáko,*+Màá sì sọ àwọn ìlú Júdà di ahoro, tí ẹnikẹ́ni kò ní gbé ibẹ̀.+
34 “‘Nígbà yẹn, ilẹ̀ náà yóò san àwọn sábáàtì rẹ̀ ní gbogbo ọjọ́ tó bá fi wà ní ahoro, nígbà tí ẹ bá wà ní ilẹ̀ àwọn ọ̀tá yín. Nígbà yẹn, ilẹ̀ náà máa sinmi,* torí ó gbọ́dọ̀ san àwọn sábáàtì rẹ̀ pa dà.+
11 Màá sọ Jerúsálẹ́mù di òkìtì òkúta,+ ibùgbé àwọn ajáko,*+Màá sì sọ àwọn ìlú Júdà di ahoro, tí ẹnikẹ́ni kò ní gbé ibẹ̀.+