Sáàmù 79:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 79 Ọlọ́run, àwọn orílẹ̀-èdè ti ya wọnú ogún rẹ;+Wọ́n ti sọ tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ di ẹlẹ́gbin;+Wọ́n ti sọ Jerúsálẹ́mù di àwókù.+ Jeremáyà 26:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “Míkà+ ti Móréṣétì sọ tẹ́lẹ̀ nígbà ayé Hẹsikáyà+ ọba Júdà, ó sì sọ fún gbogbo èèyàn Júdà pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Wọ́n á túlẹ̀ Síónì bíi pápá,Jerúsálẹ́mù á di àwókù,+Òkè Ilé* náà á sì dà bí àwọn ibi gíga nínú igbó.”’*+
79 Ọlọ́run, àwọn orílẹ̀-èdè ti ya wọnú ogún rẹ;+Wọ́n ti sọ tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ di ẹlẹ́gbin;+Wọ́n ti sọ Jerúsálẹ́mù di àwókù.+
18 “Míkà+ ti Móréṣétì sọ tẹ́lẹ̀ nígbà ayé Hẹsikáyà+ ọba Júdà, ó sì sọ fún gbogbo èèyàn Júdà pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Wọ́n á túlẹ̀ Síónì bíi pápá,Jerúsálẹ́mù á di àwókù,+Òkè Ilé* náà á sì dà bí àwọn ibi gíga nínú igbó.”’*+