Sáàmù 79:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 79 Ọlọ́run, àwọn orílẹ̀-èdè ti ya wọnú ogún rẹ;+Wọ́n ti sọ tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ di ẹlẹ́gbin;+Wọ́n ti sọ Jerúsálẹ́mù di àwókù.+ Jeremáyà 9:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Màá sọ Jerúsálẹ́mù di òkìtì òkúta,+ ibùgbé àwọn ajáko,*+Màá sì sọ àwọn ìlú Júdà di ahoro, tí ẹnikẹ́ni kò ní gbé ibẹ̀.+
79 Ọlọ́run, àwọn orílẹ̀-èdè ti ya wọnú ogún rẹ;+Wọ́n ti sọ tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ di ẹlẹ́gbin;+Wọ́n ti sọ Jerúsálẹ́mù di àwókù.+
11 Màá sọ Jerúsálẹ́mù di òkìtì òkúta,+ ibùgbé àwọn ajáko,*+Màá sì sọ àwọn ìlú Júdà di ahoro, tí ẹnikẹ́ni kò ní gbé ibẹ̀.+