Àìsáyà 27:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Igbe tó ń dẹ́rù bani lo máa fi bá a fà á nígbà tí o bá lé e lọ. Atẹ́gùn rẹ̀ tó le ló máa fi lé e jáde ní ọjọ́ afẹ́fẹ́ ìlà oòrùn.+
8 Igbe tó ń dẹ́rù bani lo máa fi bá a fà á nígbà tí o bá lé e lọ. Atẹ́gùn rẹ̀ tó le ló máa fi lé e jáde ní ọjọ́ afẹ́fẹ́ ìlà oòrùn.+