-
Léfítíkù 20:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Ẹ gbọ́dọ̀ pa ọmọ Ísírẹ́lì àti àjèjì èyíkéyìí tó ń gbé ní Ísírẹ́lì tó bá fún Mólékì ní ìkankan nínú àwọn ọmọ rẹ̀.+ Kí àwọn èèyàn ilẹ̀ náà sọ ọ́ lókùúta pa. 3 Èmi fúnra mi kò ní fi ojú rere wo ọkùnrin yẹn, màá sì pa á, kí n lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀, torí ó ti fún Mólékì lára àwọn ọmọ rẹ̀, ó ti sọ ibi mímọ́+ mi di ẹlẹ́gbin, ó sì ti sọ orúkọ mímọ́ mi di aláìmọ́.
-