Diutarónómì 28:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Jèhófà máa mú kí àrùn ṣe ọ́ títí ó fi máa pa ọ́ run ní ilẹ̀ tí o fẹ́ lọ gbà.+ 22 Jèhófà máa fi ikọ́ ẹ̀gbẹ kọ lù ọ́, pẹ̀lú akọ ibà,+ ara wíwú, ara gbígbóná, idà,+ ooru tó ń jó nǹkan gbẹ àti èbíbu;+ wọ́n á sì bá ọ títí o fi máa ṣègbé.
21 Jèhófà máa mú kí àrùn ṣe ọ́ títí ó fi máa pa ọ́ run ní ilẹ̀ tí o fẹ́ lọ gbà.+ 22 Jèhófà máa fi ikọ́ ẹ̀gbẹ kọ lù ọ́, pẹ̀lú akọ ibà,+ ara wíwú, ara gbígbóná, idà,+ ooru tó ń jó nǹkan gbẹ àti èbíbu;+ wọ́n á sì bá ọ títí o fi máa ṣègbé.