-
Ìsíkíẹ́lì 23:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Àmọ́, ó túbọ̀ ń ṣèṣekúṣe. Ó rí ère àwọn ọkùnrin tí wọ́n gbẹ́ sára ògiri, ère àwọn ará Kálídíà tí wọ́n kùn ní àwọ̀ pupa,
-
-
Ìsíkíẹ́lì 23:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Bó ṣe rí wọn, ṣe ni ọkàn rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí í fà sí wọn láti bá wọn ṣèṣekúṣe, ó sì rán àwọn òjíṣẹ́ sí wọn ní Kálídíà.+
-