Ìsíkíẹ́lì 16:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 O tún lọ ṣèṣekúṣe ní ilẹ̀ àwọn oníṣòwò* àti lọ́dọ̀ àwọn ará Kálídíà,+ síbẹ̀, kò tẹ́ ọ lọ́rùn.