2 Kíróníkà 36:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Àwọn èèyàn ilẹ̀ náà mú Jèhóáhásì+ ọmọ Jòsáyà, wọ́n sì fi í jọba ní Jerúsálẹ́mù ní ipò bàbá rẹ̀.+