Ẹ́kísódù 23:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Má ṣe gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀, torí àbẹ̀tẹ́lẹ̀ máa ń dí àwọn tó ríran kedere lójú, ó sì lè mú kí àwọn olódodo yí ọ̀rọ̀ po.+ Diutarónómì 27:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ láti pa ẹni tí kò mọwọ́ mẹsẹ̀.’*+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’) Àìsáyà 1:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Alágídí ni àwọn ìjòyè rẹ, àwọn àtàwọn olè jọ ń ṣiṣẹ́.+ Gbogbo wọn ló fẹ́ràn àbẹ̀tẹ́lẹ̀, wọ́n sì ń wá ẹ̀bùn kiri.+ Wọn kì í dá ẹjọ́ àwọn ọmọ aláìníbaba* bó ṣe tọ́,Ẹjọ́ opó kì í sì í dé iwájú wọn.+
8 “Má ṣe gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀, torí àbẹ̀tẹ́lẹ̀ máa ń dí àwọn tó ríran kedere lójú, ó sì lè mú kí àwọn olódodo yí ọ̀rọ̀ po.+
25 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ láti pa ẹni tí kò mọwọ́ mẹsẹ̀.’*+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)
23 Alágídí ni àwọn ìjòyè rẹ, àwọn àtàwọn olè jọ ń ṣiṣẹ́.+ Gbogbo wọn ló fẹ́ràn àbẹ̀tẹ́lẹ̀, wọ́n sì ń wá ẹ̀bùn kiri.+ Wọn kì í dá ẹjọ́ àwọn ọmọ aláìníbaba* bó ṣe tọ́,Ẹjọ́ opó kì í sì í dé iwájú wọn.+