Hósíà 2:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí ìyá wọn ti ṣe ìṣekúṣe.*+ Ẹni tó lóyún wọn ti hùwà àìnítìjú,+ torí ó sọ pé,‘Màá lọ bá àwọn olólùfẹ́ mi àtàtà,+Àwọn tó ń fún mi ní oúnjẹ àti omi,Irun àgùntàn àti aṣọ ọ̀gbọ̀,* òróró àti ohun mímu.’
5 Nítorí ìyá wọn ti ṣe ìṣekúṣe.*+ Ẹni tó lóyún wọn ti hùwà àìnítìjú,+ torí ó sọ pé,‘Màá lọ bá àwọn olólùfẹ́ mi àtàtà,+Àwọn tó ń fún mi ní oúnjẹ àti omi,Irun àgùntàn àti aṣọ ọ̀gbọ̀,* òróró àti ohun mímu.’