ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 32:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Ní gbogbo àkókò yẹn, àwọn èèyàn náà rí i pé Mósè ń pẹ́ lórí òkè náà.+ Àwọn èèyàn náà wá yí Áárónì ká, wọ́n sì sọ fún un pé: “Ó yá, ṣe ọlọ́run kan fún wa tó máa ṣáájú wa,+ torí a ò mọ ohun tó ti ṣẹlẹ̀ sí Mósè yìí, ẹni tó kó wa kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.”

  • Ẹ́kísódù 32:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ó gba wúrà náà lọ́wọ́ wọn, ó lo irinṣẹ́ àwọn tó ń fín nǹkan láti fi mọ ọ́n, ó sì fi ṣe ère* ọmọ màlúù.+ Wọ́n wá ń sọ pé: “Ìwọ Ísírẹ́lì, Ọlọ́run rẹ nìyí, òun ló mú ọ kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.”+

  • 1 Àwọn Ọba 12:28, 29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Lẹ́yìn tí ọba gba ìmọ̀ràn, ó ṣe ère ọmọ màlúù wúrà méjì,+ ó sì sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Wàhálà yìí ti pọ̀ jù fún yín láti máa lọ sí Jerúsálẹ́mù. Ọlọ́run rẹ rèé, ìwọ Ísírẹ́lì, tí ó mú ọ jáde kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.”+ 29 Ìgbà náà ni ó gbé ọ̀kan sí Bẹ́tẹ́lì,+ ó sì gbé ìkejì sí Dánì.+

  • 2 Àwọn Ọba 10:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Àmọ́, Jéhù ò kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ tí Jèróbóámù ọmọ Nébátì mú kí Ísírẹ́lì dá, ìyẹn jíjọ́sìn àwọn ọmọ màlúù wúrà tó wà ní Bẹ́tẹ́lì àti Dánì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́