-
Ìsíkíẹ́lì 11:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 “Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Òkú àwọn èèyàn tí ẹ fọ́n ká sí ìlú náà ni ẹran, ìlú náà sì ni ìkòkò oúnjẹ.+ Àmọ́ wọ́n máa mú ẹ̀yin alára kúrò níbẹ̀.’”
-
-
Ìsíkíẹ́lì 11:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 ‘Èmi yóò mú yín jáde kúrò nínú rẹ̀, màá mú kí ọwọ́ àwọn àjèjì tẹ̀ yín, màá sì dá yín lẹ́jọ́.+
-