Jeremáyà 16:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘Má wọnú ilé tí àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ ti ń jẹ àsè,Má lọ bá wọn pohùn réré ẹkún, má sì bá wọn kẹ́dùn.’+ ‘Torí mo ti mú àlàáfíà mi kúrò lọ́dọ̀ àwọn èèyàn yìí,’ ni Jèhófà wí,‘Títí kan ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ àti àánú mi.+
5 Nítorí ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘Má wọnú ilé tí àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ ti ń jẹ àsè,Má lọ bá wọn pohùn réré ẹkún, má sì bá wọn kẹ́dùn.’+ ‘Torí mo ti mú àlàáfíà mi kúrò lọ́dọ̀ àwọn èèyàn yìí,’ ni Jèhófà wí,‘Títí kan ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ àti àánú mi.+