Diutarónómì 31:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Màá bínú sí wọn gidigidi nígbà yẹn,+ màá pa wọ́n tì,+ màá sì fi ojú mi pa mọ́ fún wọn+ títí wọ́n á fi pa run. Tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àjálù àti wàhálà bá wá dé bá wọn,+ wọ́n á sọ pé, ‘Ṣebí torí Ọlọ́run wa ò sí láàárín wa ni àjálù yìí ṣe dé bá wa?’+ Àìsáyà 27:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nígbà tí àwọn ẹ̀ka igi rẹ̀ bá ti gbẹ,Àwọn obìnrin máa wá ṣẹ́ wọn,Wọ́n á sì fi dáná. Torí àwọn èèyàn yìí ò ní òye.+ Ìdí nìyẹn tí Aṣẹ̀dá wọn ò fi ní ṣàánú wọn rárá,Ẹni tó dá wọn ò sì ní ṣojúure kankan sí wọn.+ Àìsáyà 63:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́ wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i,+ wọ́n sì kó ẹ̀dùn ọkàn bá ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀.+ Ó wá di ọ̀tá wọn,+Ó sì bá wọn jà.+
17 Màá bínú sí wọn gidigidi nígbà yẹn,+ màá pa wọ́n tì,+ màá sì fi ojú mi pa mọ́ fún wọn+ títí wọ́n á fi pa run. Tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àjálù àti wàhálà bá wá dé bá wọn,+ wọ́n á sọ pé, ‘Ṣebí torí Ọlọ́run wa ò sí láàárín wa ni àjálù yìí ṣe dé bá wa?’+
11 Nígbà tí àwọn ẹ̀ka igi rẹ̀ bá ti gbẹ,Àwọn obìnrin máa wá ṣẹ́ wọn,Wọ́n á sì fi dáná. Torí àwọn èèyàn yìí ò ní òye.+ Ìdí nìyẹn tí Aṣẹ̀dá wọn ò fi ní ṣàánú wọn rárá,Ẹni tó dá wọn ò sì ní ṣojúure kankan sí wọn.+
10 Àmọ́ wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí i,+ wọ́n sì kó ẹ̀dùn ọkàn bá ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀.+ Ó wá di ọ̀tá wọn,+Ó sì bá wọn jà.+