Jeremáyà 47:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nítorí ọjọ́ ń bọ̀ tí gbogbo Filísínì máa pa run;+Gbogbo olùrànlọ́wọ́ tó ṣẹ́ kù ní Tírè+ àti Sídónì+ la máa gé kúrò. Nítorí Jèhófà máa pa àwọn Filísínì run,Àwọn tó ṣẹ́ kù láti erékùṣù Káfítórì.*+
4 Nítorí ọjọ́ ń bọ̀ tí gbogbo Filísínì máa pa run;+Gbogbo olùrànlọ́wọ́ tó ṣẹ́ kù ní Tírè+ àti Sídónì+ la máa gé kúrò. Nítorí Jèhófà máa pa àwọn Filísínì run,Àwọn tó ṣẹ́ kù láti erékùṣù Káfítórì.*+