ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 23:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Ó ti na ọwọ́ rẹ̀ sórí òkun;

      Ó ti mi àwọn ìjọba jìgìjìgì.

      Jèhófà ti pàṣẹ pé kí wọ́n pa àwọn ibi ààbò Foníṣíà run.+

  • Émọ́sì 1:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Torí náà, màá rán iná sí ògiri Tírè,

      Á sì jó àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò run.’+

  • Sekaráyà 9:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Wò ó! Jèhófà máa gba àwọn ohun ìní rẹ̀,

      Yóò sì run àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sínú òkun;*+

      Iná yóò sì jẹ ẹ́ run.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́