-
Ìsíkíẹ́lì 10:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Bí mo ṣe ń wò, mo rí àgbá kẹ̀kẹ́ mẹ́rin lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn kérúbù náà, àgbá kẹ̀kẹ́ kan lẹ́gbẹ̀ẹ́ kérúbù kọ̀ọ̀kan, àwọn àgbá náà ń dán bí òkúta kírísóláítì.+
-