ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 23:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun fúnra rẹ̀ ti pinnu èyí,

      Láti tẹ́ńbẹ́lú bó ṣe ń fi gbogbo ẹwà rẹ̀ yangàn,

      Láti rẹ gbogbo àwọn tí wọ́n ń bọlá fún ní ayé sílẹ̀.+

  • Jeremáyà 25:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Torí náà, mo gba ife náà lọ́wọ́ Jèhófà, mo sì mú kí gbogbo orílẹ̀-èdè tí Jèhófà rán mi sí mu ún:+

  • Jeremáyà 25:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 gbogbo ọba Tírè, gbogbo ọba Sídónì+ àti àwọn ọba erékùṣù tó wà ní ẹ̀gbẹ́ òkun,

  • Jeremáyà 47:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Nítorí ọjọ́ ń bọ̀ tí gbogbo Filísínì máa pa run;+

      Gbogbo olùrànlọ́wọ́ tó ṣẹ́ kù ní Tírè+ àti Sídónì+ la máa gé kúrò.

      Nítorí Jèhófà máa pa àwọn Filísínì run,

      Àwọn tó ṣẹ́ kù láti erékùṣù Káfítórì.*+

  • Jóẹ́lì 3:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Èmi yóò ta àwọn ọmọ yín ọkùnrin àti obìnrin fún àwọn ará Júdà,+

      Wọn yóò sì tà wọ́n fún àwọn ará Ṣébà, orílẹ̀-èdè tó jìnnà réré;

      Jèhófà fúnra rẹ̀ ti sọ ọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́