-
Ìsíkíẹ́lì 12:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Gbé ẹrù rẹ lé èjìká níṣojú wọn, kí o sì gbé e jáde nínú òkùnkùn. Bo ojú rẹ kí o má bàa rí ilẹ̀, torí èmi yóò fi ọ́ ṣe àmì fún ilé Ísírẹ́lì.”+
-
-
Ìsíkíẹ́lì 24:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Ìsíkíẹ́lì ti di àmì fún yín.+ Ohun tó ṣe ni ẹ̀yin náà yóò ṣe. Nígbà tó bá rí bẹ́ẹ̀, ẹ ó wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ.’”’”
-