3 Jèhófà wá sọ pé: “Bí ìránṣẹ́ mi Àìsáyà ṣe rìn káàkiri ní ìhòòhò, láìwọ bàtà fún ọdún mẹ́ta, láti fi ṣe àmì+ àti àpẹẹrẹ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí Íjíbítì+ àti Etiópíà,+
3 Gbé agbada onírin, kí o sì fi ṣe ògiri onírin láàárín ìwọ àti ìlú náà. Kí o wá dojú kọ ọ́, kí a sì dó tì í; ìwọ ni kí o dó tì í. Àmì ni èyí jẹ́ fún ilé Ísírẹ́lì.+