ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 46:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “Sọ ọ́ ní Íjíbítì, sì kéde rẹ̀ ní Mígídólì.+

      Kéde rẹ̀ ní Nófì* àti ní Tápánẹ́sì.+

      Sọ pé, ‘Ẹ dúró sí àyè yín, kí ẹ sì múra sílẹ̀,

      Nítorí idà kan máa pani run ní gbogbo àyíká yín.

  • Ìsíkíẹ́lì 30:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Idà yóò dojú kọ Íjíbítì, ìbẹ̀rù á sì bo Etiópíà nígbà tí òkú bá sùn ní Íjíbítì;

      Wọ́n ti kó ọrọ̀ rẹ̀, wọ́n sì ti wó ìpìlẹ̀ rẹ̀.+

  • Ìsíkíẹ́lì 32:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Èmi yóò mú kí idà àwọn jagunjagun tó lákíkanjú pa ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èèyàn rẹ,

      Àwọn tó burú jù láàárín àwọn orílẹ̀-èdè, gbogbo wọn.+

      Wọ́n á rẹ ìgbéraga Íjíbítì wálẹ̀, wọ́n á sì run gbogbo èèyàn rẹ̀ tó pọ̀ rẹpẹtẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́