Jeremáyà 43:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Màá sọ iná sí ilé* àwọn ọlọ́run Íjíbítì, ọba náà á sun wọ́n,+ á sì kó wọn lọ sí oko ẹrú. Á da ilẹ̀ Íjíbítì bora bí olùṣọ́ àgùntàn ti ń da ẹ̀wù bo ara rẹ̀, á sì jáde kúrò níbẹ̀ ní àlàáfíà.* Jeremáyà 46:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Sọ ọ́ ní Íjíbítì, sì kéde rẹ̀ ní Mígídólì.+ Kéde rẹ̀ ní Nófì* àti ní Tápánẹ́sì.+ Sọ pé, ‘Ẹ dúró sí àyè yín, kí ẹ sì múra sílẹ̀,Nítorí idà kan máa pani run ní gbogbo àyíká yín.
12 Màá sọ iná sí ilé* àwọn ọlọ́run Íjíbítì, ọba náà á sun wọ́n,+ á sì kó wọn lọ sí oko ẹrú. Á da ilẹ̀ Íjíbítì bora bí olùṣọ́ àgùntàn ti ń da ẹ̀wù bo ara rẹ̀, á sì jáde kúrò níbẹ̀ ní àlàáfíà.*
14 “Sọ ọ́ ní Íjíbítì, sì kéde rẹ̀ ní Mígídólì.+ Kéde rẹ̀ ní Nófì* àti ní Tápánẹ́sì.+ Sọ pé, ‘Ẹ dúró sí àyè yín, kí ẹ sì múra sílẹ̀,Nítorí idà kan máa pani run ní gbogbo àyíká yín.