Ìsíkíẹ́lì 32:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Èmi yóò ju ẹran rẹ sórí àwọn òkè,Màá sì fi ara rẹ tó ṣẹ́ kù kún inú àwọn àfonífojì.+ 6 Màá fi ẹ̀jẹ̀ rẹ tó ń tú jáde rin ilẹ̀ náà títí dé orí àwọn òkè,Yóò sì kún inú àwọn odò.’*
5 Èmi yóò ju ẹran rẹ sórí àwọn òkè,Màá sì fi ara rẹ tó ṣẹ́ kù kún inú àwọn àfonífojì.+ 6 Màá fi ẹ̀jẹ̀ rẹ tó ń tú jáde rin ilẹ̀ náà títí dé orí àwọn òkè,Yóò sì kún inú àwọn odò.’*