-
Ìsíkíẹ́lì 31:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Àwọn àjèjì, àwọn tó burú jù láàárín àwọn orílẹ̀-èdè, yóò gé e lulẹ̀, wọ́n á sì pa á tì sórí àwọn òkè, àwọn ewé rẹ̀ á já bọ́ sí gbogbo àfonífojì, àwọn ẹ̀ka rẹ̀ á sì ṣẹ́ sínú gbogbo odò ilẹ̀ náà.+ Gbogbo èèyàn ayé yóò kúrò lábẹ́ ibòji rẹ̀, wọ́n á sì pa á tì.
-