Àìsáyà 21:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ó wá ké jáde bíi kìnnìún, ó ní: “Jèhófà, orí ilé ìṣọ́ ni mò ń dúró sí nígbà gbogbo ní ọ̀sán,Mi ò sì kúrò níbi tí a fi mí ṣọ́ ní gbogbo òru.+ Jeremáyà 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́, gbára dì,*Kí o sì dìde láti bá wọn sọ gbogbo ohun tí mo bá pa láṣẹ fún ọ. Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù wọn bà ọ́,+Kí n má bàa jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́ níwájú wọn. Ìsíkíẹ́lì 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Ọmọ èèyàn, mo ti fi ọ́ ṣe olùṣọ́ fún ilé Ísírẹ́lì,+ nígbà tí o bá gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹnu mi, kí o bá mi kìlọ̀ fún wọn.+
8 Ó wá ké jáde bíi kìnnìún, ó ní: “Jèhófà, orí ilé ìṣọ́ ni mò ń dúró sí nígbà gbogbo ní ọ̀sán,Mi ò sì kúrò níbi tí a fi mí ṣọ́ ní gbogbo òru.+
17 Àmọ́, gbára dì,*Kí o sì dìde láti bá wọn sọ gbogbo ohun tí mo bá pa láṣẹ fún ọ. Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù wọn bà ọ́,+Kí n má bàa jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́ níwájú wọn.
17 “Ọmọ èèyàn, mo ti fi ọ́ ṣe olùṣọ́ fún ilé Ísírẹ́lì,+ nígbà tí o bá gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹnu mi, kí o bá mi kìlọ̀ fún wọn.+