-
1 Àwọn Ọba 8:50Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
50 kí o dárí ji àwọn èèyàn rẹ tó ṣẹ̀ ọ́, kí o dárí gbogbo bí wọ́n ṣe tẹ ìlànà rẹ lójú jì wọ́n. Kí o jẹ́ kí wọ́n rójú àánú àwọn tó kó wọn lẹ́rú, kí wọ́n sì ṣàánú wọn+
-