-
Léfítíkù 6:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Tó bá ti ṣẹ̀, tó sì jẹ̀bi, kó dá ohun tó jí pa dà àti ohun tó fipá gbà, ohun tó fi jìbìtì gbà, ohun tí wọ́n fi sí ìkáwọ́ rẹ̀ tàbí ohun tó sọ nù tí ó rí,
-
-
Ìsíkíẹ́lì 22:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Àwọn èèyàn ilẹ̀ náà ti lu jìbìtì, wọ́n sì ti jalè,+ wọ́n ti ni aláìní àti tálákà lára, wọ́n ti lu àjèjì ní jìbìtì, wọ́n sì ti fi ẹ̀tọ́ rẹ̀ dù ú.’
-