ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 28:49, 50
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 49 “Jèhófà máa gbé orílẹ̀-èdè kan tó wà lọ́nà jíjìn+ dìde sí ọ, láti ìkángun ayé; ó máa kì ọ́ mọ́lẹ̀ bí ẹyẹ idì+ ṣe ń ṣe, orílẹ̀-èdè tí o ò ní gbọ́+ èdè rẹ̀, 50 orílẹ̀-èdè tí ojú rẹ̀ le gan-an, tí kò ní wo ojú arúgbó, tí kò sì ní ṣojúure sí àwọn ọmọdé.+

  • Jeremáyà 48:40
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 40 “Nítorí ohun tí Jèhófà sọ nìyí:

      ‘Wò ó! Bí ẹyẹ idì ṣe ń já ṣòòrò wálẹ̀,+

      Ni ọ̀tá ṣe máa na ìyẹ́ rẹ̀ bo Móábù.+

  • Ìdárò 4:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Àwọn tó ń lé wa yára ju ẹyẹ idì ojú ọ̀run lọ.+

      Wọ́n lépa wa lórí àwọn òkè; wọ́n lúgọ dè wá nínú aginjù.

  • Hábákúkù 1:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Àwọn ẹṣin wọn yára ju àmọ̀tẹ́kùn lọ,

      Wọ́n sì burú ju ìkookò ní alẹ́.+

      Àwọn ẹṣin ogun wọn ń bẹ́ gìjàgìjà;

      Ọ̀nà jíjìn làwọn ẹṣin wọn ti wá.

      Wọ́n já ṣòòrò wálẹ̀ bí ẹyẹ idì tó fẹ́ yára gbé oúnjẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́