Dáníẹ́lì 2:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 “Àmọ́ ìjọba míì máa dìde lẹ́yìn rẹ,+ tí kò tó ọ; lẹ́yìn èyí ni ìjọba míì, ìkẹta, tó jẹ́ bàbà, tó máa ṣàkóso gbogbo ayé.+ Dáníẹ́lì 8:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bí mo ṣe ń wò, mo rí òbúkọ+ kan tó ń bọ̀ láti ìwọ̀ oòrùn,* ó ń kọjá lọ ní gbogbo ayé láìfi ẹsẹ̀ kanlẹ̀. Òbúkọ náà sì ní ìwo kan tó hàn kedere láàárín àwọn ojú rẹ̀.+ Dáníẹ́lì 11:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Ọba kan tó lágbára máa dìde, ìṣàkóso rẹ̀ máa gbilẹ̀,+ á sì máa ṣe ohun tó wù ú.
39 “Àmọ́ ìjọba míì máa dìde lẹ́yìn rẹ,+ tí kò tó ọ; lẹ́yìn èyí ni ìjọba míì, ìkẹta, tó jẹ́ bàbà, tó máa ṣàkóso gbogbo ayé.+
5 Bí mo ṣe ń wò, mo rí òbúkọ+ kan tó ń bọ̀ láti ìwọ̀ oòrùn,* ó ń kọjá lọ ní gbogbo ayé láìfi ẹsẹ̀ kanlẹ̀. Òbúkọ náà sì ní ìwo kan tó hàn kedere láàárín àwọn ojú rẹ̀.+