Dáníẹ́lì 2:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 “Àmọ́ ìjọba míì máa dìde lẹ́yìn rẹ,+ tí kò tó ọ; lẹ́yìn èyí ni ìjọba míì, ìkẹta, tó jẹ́ bàbà, tó máa ṣàkóso gbogbo ayé.+ Dáníẹ́lì 7:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Lẹ́yìn èyí, mò ń wò, sì wò ó! ẹranko míì tó dà bí àmọ̀tẹ́kùn,+ àmọ́ tó ní ìyẹ́ mẹ́rin bíi ti ẹyẹ ní ẹ̀yìn rẹ̀. Ẹranko náà ní orí mẹ́rin,+ a sì fún un ní àṣẹ láti ṣàkóso. Dáníẹ́lì 8:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Òbúkọ onírun náà dúró fún ọba ilẹ̀ Gíríìsì;+ ìwo ńlá tó wà láàárín àwọn ojú rẹ̀ sì dúró fún ọba àkọ́kọ́.+
39 “Àmọ́ ìjọba míì máa dìde lẹ́yìn rẹ,+ tí kò tó ọ; lẹ́yìn èyí ni ìjọba míì, ìkẹta, tó jẹ́ bàbà, tó máa ṣàkóso gbogbo ayé.+
6 “Lẹ́yìn èyí, mò ń wò, sì wò ó! ẹranko míì tó dà bí àmọ̀tẹ́kùn,+ àmọ́ tó ní ìyẹ́ mẹ́rin bíi ti ẹyẹ ní ẹ̀yìn rẹ̀. Ẹranko náà ní orí mẹ́rin,+ a sì fún un ní àṣẹ láti ṣàkóso.
21 Òbúkọ onírun náà dúró fún ọba ilẹ̀ Gíríìsì;+ ìwo ńlá tó wà láàárín àwọn ojú rẹ̀ sì dúró fún ọba àkọ́kọ́.+