ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 33:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Ó sọ pé:

      “Jèhófà wá láti Sínáì,+

      Ó sì tàn sórí wọn láti Séírì.

      Ògo rẹ̀ tàn láti agbègbè olókè Páránì,+

      Ọ̀kẹ́ àìmọye* àwọn ẹni mímọ́+ sì wà pẹ̀lú rẹ̀,

      Àwọn jagunjagun+ rẹ̀ wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀.

  • 1 Àwọn Ọba 22:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Mikáyà bá sọ pé: “Nítorí náà, gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà: Mo rí Jèhófà tó jókòó sórí ìtẹ́ rẹ̀,+ gbogbo ọmọ ogun ọ̀run sì dúró sẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, lápá ọ̀tún àti lápá òsì.+

  • Sáàmù 68:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Àwọn kẹ̀kẹ́ ogun Ọlọ́run jẹ́ ẹgbẹẹgbàárùn-ún, ẹgbẹẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹgbẹẹgbẹ̀rún.+

      Jèhófà wá láti Sínáì sínú ibi mímọ́.+

  • Hébérù 12:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Àmọ́ ẹ ti sún mọ́ Òkè Síónì+ àti ìlú Ọlọ́run alààyè, Jerúsálẹ́mù ti ọ̀run+ àti ọ̀kẹ́ àìmọye* àwọn áńgẹ́lì

  • Júùdù 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Kódà, Énọ́kù+ tó jẹ́ ẹnì keje nínú ìran Ádámù tún sọ tẹ́lẹ̀ nípa wọn pé: “Wò ó! Jèhófà* dé pẹ̀lú ọ̀kẹ́ àìmọye* àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀,+

  • Ìfihàn 5:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Mo rí ọ̀pọ̀ áńgẹ́lì, mo sì gbọ́ ohùn wọn, wọ́n wà yí ká ìtẹ́ náà àti àwọn ẹ̀dá alààyè àti àwọn àgbààgbà náà, iye wọn jẹ́ ẹgbẹẹgbàárùn-ún lọ́nà ẹgbẹẹgbàárùn-ún* àti ẹgbẹẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹgbẹẹgbẹ̀rún,+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́