-
Dáníẹ́lì 7:10, 11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Iná ń ṣàn jáde lọ níwájú rẹ̀.+ Ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹgbẹẹgbẹ̀rún ń ṣe ìránṣẹ́ fún un, ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá lọ́nà ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá sì dúró níwájú rẹ̀.+ Kọ́ọ̀tù+ jókòó, a sì ṣí àwọn ìwé.
11 “Mò ń wò nígbà yẹn torí bí mo ṣe ń gbọ́ àwọn ọ̀rọ̀ ìgbéraga* tí ìwo náà ń sọ;+ mò ń wò ó títí a fi pa ẹranko náà, tí a pa ara rẹ̀ run, a sì jù ú sínú iná kó lè jó o.
-