Sáàmù 48:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Gíga rẹ̀ rẹwà, ayọ̀ gbogbo ayé,+Òkè Síónì tó jìnnà réré ní àríwá,Ìlú Ọba Títóbi Lọ́lá.+ Dáníẹ́lì 11:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ẹni tó ń bọ̀ láti gbéjà kò ó máa ṣe ohun tó wù ú, kò sì ní sẹ́ni tó máa dúró níwájú rẹ̀. Ó máa dúró ní ilẹ̀ Ìṣelọ́ṣọ̀ọ́,*+ agbára láti pani run sì máa wà ní ọwọ́ rẹ̀. Dáníẹ́lì 11:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Ó máa pa àwọn àgọ́ ọba rẹ̀* sáàárín òkun ńlá àti òkè mímọ́ Ìṣelọ́ṣọ̀ọ́;*+ ó máa wá pa run, kò sì ní sẹ́ni tó máa ràn án lọ́wọ́.
16 Ẹni tó ń bọ̀ láti gbéjà kò ó máa ṣe ohun tó wù ú, kò sì ní sẹ́ni tó máa dúró níwájú rẹ̀. Ó máa dúró ní ilẹ̀ Ìṣelọ́ṣọ̀ọ́,*+ agbára láti pani run sì máa wà ní ọwọ́ rẹ̀.
45 Ó máa pa àwọn àgọ́ ọba rẹ̀* sáàárín òkun ńlá àti òkè mímọ́ Ìṣelọ́ṣọ̀ọ́;*+ ó máa wá pa run, kò sì ní sẹ́ni tó máa ràn án lọ́wọ́.