Sáàmù 48:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Gíga rẹ̀ rẹwà, ayọ̀ gbogbo ayé,+Òkè Síónì tó jìnnà réré ní àríwá,Ìlú Ọba Títóbi Lọ́lá.+ Dáníẹ́lì 8:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ìwo míì jáde látinú ọ̀kan lára wọn, ìwo kékeré ni, ó sì di ńlá gan-an, sí apá gúúsù, sí apá ìlà oòrùn* àti sí Ìṣelọ́ṣọ̀ọ́.*+ Dáníẹ́lì 11:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Ó tún máa wọ ilẹ̀ Ìṣelọ́ṣọ̀ọ́,*+ a sì máa mú ọ̀pọ̀ ilẹ̀ kọsẹ̀. Àmọ́ àwọn tó máa bọ́ lọ́wọ́ rẹ̀ nìyí: Édómù, Móábù àti èyí tó ṣe pàtàkì jù lára àwọn ọmọ Ámónì. Dáníẹ́lì 11:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Ó máa pa àwọn àgọ́ ọba rẹ̀* sáàárín òkun ńlá àti òkè mímọ́ Ìṣelọ́ṣọ̀ọ́;*+ ó máa wá pa run, kò sì ní sẹ́ni tó máa ràn án lọ́wọ́.
9 Ìwo míì jáde látinú ọ̀kan lára wọn, ìwo kékeré ni, ó sì di ńlá gan-an, sí apá gúúsù, sí apá ìlà oòrùn* àti sí Ìṣelọ́ṣọ̀ọ́.*+
41 Ó tún máa wọ ilẹ̀ Ìṣelọ́ṣọ̀ọ́,*+ a sì máa mú ọ̀pọ̀ ilẹ̀ kọsẹ̀. Àmọ́ àwọn tó máa bọ́ lọ́wọ́ rẹ̀ nìyí: Édómù, Móábù àti èyí tó ṣe pàtàkì jù lára àwọn ọmọ Ámónì.
45 Ó máa pa àwọn àgọ́ ọba rẹ̀* sáàárín òkun ńlá àti òkè mímọ́ Ìṣelọ́ṣọ̀ọ́;*+ ó máa wá pa run, kò sì ní sẹ́ni tó máa ràn án lọ́wọ́.