Ẹ́kísódù 6:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Ní báyìí, wàá rí ohun tí màá ṣe sí Fáráò.+ Ọwọ́ agbára ló máa mú kó fi wọ́n sílẹ̀, ọwọ́ agbára ló sì máa mú kó lé wọn kúrò ní ilẹ̀ rẹ̀.”+
6 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Ní báyìí, wàá rí ohun tí màá ṣe sí Fáráò.+ Ọwọ́ agbára ló máa mú kó fi wọ́n sílẹ̀, ọwọ́ agbára ló sì máa mú kó lé wọn kúrò ní ilẹ̀ rẹ̀.”+