Éfésù 6:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 nítorí a ní ìjà* kan,+ kì í ṣe pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ àti ẹran ara, àmọ́ ó jẹ́ pẹ̀lú àwọn alákòóso, pẹ̀lú àwọn aláṣẹ, pẹ̀lú àwọn alákòóso ayé òkùnkùn yìí, pẹ̀lú agbo ọmọ ogun àwọn ẹ̀mí burúkú+ ní àwọn ibi ọ̀run.
12 nítorí a ní ìjà* kan,+ kì í ṣe pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ àti ẹran ara, àmọ́ ó jẹ́ pẹ̀lú àwọn alákòóso, pẹ̀lú àwọn aláṣẹ, pẹ̀lú àwọn alákòóso ayé òkùnkùn yìí, pẹ̀lú agbo ọmọ ogun àwọn ẹ̀mí burúkú+ ní àwọn ibi ọ̀run.