Dáníẹ́lì 8:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ó gbéra ga sí Olórí àwọn ọmọ ogun pàápàá, a sì mú ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nígbà gbogbo* kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀, a sì wó ibi tó fìdí múlẹ̀ ní ibi mímọ́ rẹ̀ lulẹ̀.+
11 Ó gbéra ga sí Olórí àwọn ọmọ ogun pàápàá, a sì mú ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nígbà gbogbo* kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀, a sì wó ibi tó fìdí múlẹ̀ ní ibi mímọ́ rẹ̀ lulẹ̀.+