Dáníẹ́lì 11:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Àwọn ọmọ ogun* máa dìde, láti ọ̀dọ̀ rẹ̀; wọ́n máa sọ ibi mímọ́, ibi ààbò, di aláìmọ́,+ wọ́n sì máa mú ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nígbà gbogbo* kúrò.+ “Wọ́n máa gbé ohun ìríra tó ń fa ìsọdahoro kalẹ̀.+ Dáníẹ́lì 12:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Látìgbà tí a bá ti mú ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nígbà gbogbo*+ kúrò, tí a sì ti gbé ohun ìríra tó ń fa ìsọdahoro kalẹ̀,+ ẹgbẹ̀rún kan ó lé igba àti àádọ́rùn-ún (1,290) ọjọ́ máa wà.
31 Àwọn ọmọ ogun* máa dìde, láti ọ̀dọ̀ rẹ̀; wọ́n máa sọ ibi mímọ́, ibi ààbò, di aláìmọ́,+ wọ́n sì máa mú ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nígbà gbogbo* kúrò.+ “Wọ́n máa gbé ohun ìríra tó ń fa ìsọdahoro kalẹ̀.+
11 “Látìgbà tí a bá ti mú ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nígbà gbogbo*+ kúrò, tí a sì ti gbé ohun ìríra tó ń fa ìsọdahoro kalẹ̀,+ ẹgbẹ̀rún kan ó lé igba àti àádọ́rùn-ún (1,290) ọjọ́ máa wà.