Àìsáyà 5:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn tó ń dìde mu ọtí láàárọ̀ kùtù gbé,+Tí wọ́n ń dúró síbẹ̀ dìgbà tílẹ̀ ṣú títí ọtí fi ń pa wọ́n! Àìsáyà 28:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Adé* ìgbéraga* àwọn ọ̀mùtípara Éfúrémù+ gbéÀti ìtànná ẹwà ológo rẹ̀ tó ti ń rọ,Tó wà ní orí àfonífojì ọlọ́ràá tó jẹ́ ti àwọn tí wáìnì ti kápá wọn!
11 Àwọn tó ń dìde mu ọtí láàárọ̀ kùtù gbé,+Tí wọ́n ń dúró síbẹ̀ dìgbà tílẹ̀ ṣú títí ọtí fi ń pa wọ́n!
28 Adé* ìgbéraga* àwọn ọ̀mùtípara Éfúrémù+ gbéÀti ìtànná ẹwà ológo rẹ̀ tó ti ń rọ,Tó wà ní orí àfonífojì ọlọ́ràá tó jẹ́ ti àwọn tí wáìnì ti kápá wọn!