Àìsáyà 48:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Gbọ́ èyí, ìwọ ilé Jékọ́bù,Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fi orúkọ Ísírẹ́lì pe ara yín +Àti ẹ̀yin tí ẹ jáde látinú omi* Júdà,Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fi orúkọ Jèhófà búra,+Tí ẹ sì ń ké pe Ọlọ́run Ísírẹ́lì,Bó tiẹ̀ jẹ́ pé kì í ṣe ní òtítọ́ àti òdodo.+ Míkà 3:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn olórí* rẹ̀ ń gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n tó dájọ́,+Àwọn àlùfáà rẹ̀ ń gba owó kí wọ́n tó kọ́ni,+Àwọn wòlíì rẹ̀ ń gba owó* kí wọ́n tó woṣẹ́.+ Síbẹ̀ wọ́n gbára lé Jèhófà,* wọ́n ń sọ pé: “Ṣebí Jèhófà wà pẹ̀lú wa?+ Àjálù kankan ò lè dé bá wa.”+
48 Gbọ́ èyí, ìwọ ilé Jékọ́bù,Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fi orúkọ Ísírẹ́lì pe ara yín +Àti ẹ̀yin tí ẹ jáde látinú omi* Júdà,Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fi orúkọ Jèhófà búra,+Tí ẹ sì ń ké pe Ọlọ́run Ísírẹ́lì,Bó tiẹ̀ jẹ́ pé kì í ṣe ní òtítọ́ àti òdodo.+
11 Àwọn olórí* rẹ̀ ń gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n tó dájọ́,+Àwọn àlùfáà rẹ̀ ń gba owó kí wọ́n tó kọ́ni,+Àwọn wòlíì rẹ̀ ń gba owó* kí wọ́n tó woṣẹ́.+ Síbẹ̀ wọ́n gbára lé Jèhófà,* wọ́n ń sọ pé: “Ṣebí Jèhófà wà pẹ̀lú wa?+ Àjálù kankan ò lè dé bá wa.”+