-
Àìsáyà 21:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Torí ohun tí Jèhófà sọ fún mi nìyí:
“Lọ, yan aṣọ́nà, kí o sì ní kó ròyìn ohun tó bá rí.”
-
-
Jeremáyà 6:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Àmọ́ wọ́n sọ pé: “A ò ní fetí sí i.”+
-