Àìsáyà 31:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ó mà ṣe fún àwọn tó ń wá ìrànlọ́wọ́ lọ sọ́dọ̀ Íjíbítì o,+Tí wọ́n gbójú lé ẹṣin,+Tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ogun, torí pé wọ́n pọ̀,Àti àwọn ẹṣin ogun,* torí pé wọ́n lágbára. Wọn ò yíjú sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,Wọn ò sì wá Jèhófà.
31 Ó mà ṣe fún àwọn tó ń wá ìrànlọ́wọ́ lọ sọ́dọ̀ Íjíbítì o,+Tí wọ́n gbójú lé ẹṣin,+Tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ogun, torí pé wọ́n pọ̀,Àti àwọn ẹṣin ogun,* torí pé wọ́n lágbára. Wọn ò yíjú sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,Wọn ò sì wá Jèhófà.