-
Diutarónómì 16:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Máa ṣèdájọ́ òdodo, àní ìdájọ́ òdodo ni kí o máa ṣe,+ kí o lè máa wà láàyè, kí o sì lè gba ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa fún ọ.
-